Sáàmù 53:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ènìyàn tí ó ti yí padà,wọ́n ti parapọ̀ di ìbàjẹ́;kò sí ẹnìkan tí ó ń ṣe rere, kò sí ẹnìkan.

Sáàmù 53

Sáàmù 53:2-5