Sáàmù 53:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run bojú wo ilẹ̀ láti ọ̀runsórí àwọn ọmọ ènìyànláti wò bóyá ẹnìkan wà tí ó ní òye,tí ó sì ń wá Ọlọ́run.

Sáàmù 53

Sáàmù 53:1-6