Sáàmù 53:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé àwọn oníṣẹ́ búburú kò ní ìmọ̀?Àwọn ẹni tí ń jẹ ènìyàn mi, bí ẹni jẹuntí wọn kò sì pe Ọlọ́run?

Sáàmù 53

Sáàmù 53:1-6