Sáàmù 29:10-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Olúwa jókòó, Ó sì jọba lórí ìṣàn omi; Olúwa jókòó lórí ìtẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọbatítí láéláé.

11. Kí Olúwa fi agbára fún àwọn ènìyàn Rẹ̀;bùkún àwọn ènìyàn Rẹ̀ pẹ̀lú àlàáfíà.

Sáàmù 29