Sáàmù 29:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí Olúwa fi agbára fún àwọn ènìyàn Rẹ̀;bùkún àwọn ènìyàn Rẹ̀ pẹ̀lú àlàáfíà.

Sáàmù 29

Sáàmù 29:10-11