Sáàmù 28:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ gba àwọn ènìyàn Rẹ là, kí o sì bùkún àwọn ajogún Rẹ;di olùsọ́ àgùntàn wọn, kí o sì gbé wọn lékè títí ayérayé.

Sáàmù 28

Sáàmù 28:1-9