Sáàmù 30:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò kókìkíì Rẹ, Olúwa,nítorí ìwọ ni ó gbé mi lékètí ìwọ kò sì jẹ́ kí àwọn ọ̀ta mi kí ó yọ̀ mí.

Sáàmù 30

Sáàmù 30:1-10