Jóṣúà 15:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Olúwa pa fún Jóṣúà, ó fi ìpín fún Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè, ipin ní Júdà-Kiriati Áríbà, tí í ṣe Hébúrónì. (Áríbà sì ní baba ńlá Ánákì.)

Jóṣúà 15

Jóṣúà 15:10-17