Jóṣúà 15:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kélẹ́bù sì lé àwọn ọmọ Ánákì mẹ́ta jáde láti Hébúrónì-Ṣéṣáyì, Áhímónì, àti Tálímáì-ìran Ánákì.

Jóṣúà 15

Jóṣúà 15:4-24