Jóṣúà 15:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààlà ìwọ̀-oòrùn sì jẹ́ agbégbé Òkun ńlá.Ìwọ̀nyí ni ààlà àyíká ènìyàn Júdà ní agbo ilé wọn.

Jóṣúà 15

Jóṣúà 15:7-14