Jẹ́nẹ́sísì 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni àkọsílẹ̀ ìran Ádámù.Nígbà tí Ọlọ́run dá ènìyàn, ó dá a ní àwòrán Ọlọ́run.

Jẹ́nẹ́sísì 5

Jẹ́nẹ́sísì 5:1-8