Jẹ́nẹ́sísì 4:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣẹ́tì náà sì bí ọmọkùnrin kan, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Énọ́sì.Láti àkókò náà lọ ni àwọn ènìyàn ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ké pe orúkọ Olúwa.

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:20-26