Jẹ́nẹ́sísì 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dá wọn ní akọ àti abo, ó sì súre fún wọn. Nígbà tí ó dá wọn tan ó pè wọ́n ní “ènìyàn.”

Jẹ́nẹ́sísì 5

Jẹ́nẹ́sísì 5:1-10