Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójúkan náà, ó sì ti mú àwọn ọmọ-ogun àti àwọn balógun ọ̀rún, ó sì súré sọ̀kalẹ̀ tọ̀ wọ́n lọ; nígbà tí wọ́n sì rí í olórí ogun àti àwọn ọmọ-ogun dẹ́kun lílù Pọ́ọ̀lù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:29-35