Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọn sì ti ń wá ọ̀nà láti pa á, ìròyìn dé ọ̀dọ̀ olórí ẹgbẹ́ ọmọ-ogun pé, gbogbo Jerúsálémù dàrú.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:22-38