Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni olórí ogun súnmọ́ wọn, ó sì mú un, ó pàṣẹ pé kí a fi ẹ̀wọ̀n méjì dè é; ó sì bèèrè ẹni tí ó jẹ́, àti ohun tí ó ṣe.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:31-34