Deutarónómì 9:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo gbàdúrà sí Olúwa wí pé, “Olúwa Olódùmarè, má ṣe run àwọn ènìyàn rẹ, àní ogún rẹ tí o ti ràpadà, nípa agbára rẹ tí o sì fi agbára ńlá mú wọn jáde láti Éjíbítì wá.

Deutarónómì 9

Deutarónómì 9:24-29