Deutarónómì 9:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ti wólẹ̀ níwájú Olúwa fún ogójì ọ̀sán àti òru wọ̀nyí nítorí pé Olúwa sọ pé Òun yóò pa yín run.

Deutarónómì 9

Deutarónómì 9:19-29