Deutarónómì 9:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rántí àwọn ìránṣẹ́ rẹ Ábúráhámù, Ísáákì, àti Jákọ́bù. Fojú fo orí kunkun àwọn ènìyàn yìí, pẹ̀lú ìwà búburú àti ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Deutarónómì 9

Deutarónómì 9:26-29