Deutarónómì 33:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti Áṣérì ó wí pé:“Ìbùkún ọmọ ni ti Áṣérì;jẹ́ kí ó rí ojú rere láti ọ̀dọ̀ àwọn arákùnrin rẹ̀kí ó sì ri ẹṣẹ̀ rẹ̀ sínú òróró.

Deutarónómì 33

Deutarónómì 33:15-29