Deutarónómì 33:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bàtà rẹ̀ yóò jẹ́ irin àti idẹ,agbára rẹ̀ yóò sì rí bí ọjọ́ rẹ̀.

Deutarónómì 33

Deutarónómì 33:21-29