Deutarónómì 33:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti Náfítánì ó wí pé,“Ìwọ Náfítánì, Náfítánì kún fún ojú rere Ọlọ́runàti ìbùkún Olúwa;yóò jogún ìhà ìwọ̀ oòrùn àti gúṣù.”

Deutarónómì 33

Deutarónómì 33:18-26