Deutarónómì 27:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ègún ni fún ọkùnrin náà tí ó si afọ́jú lọ́nà ní ojú ọ̀nà.”Nígbà náà ni gbogbo ènìyàn wọ̀nyí yóò wí pé, “Àmín!”

Deutarónómì 27

Deutarónómì 27:17-19