Deutarónómì 27:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ègún ni fún ọkùnrin náà tí ó yí òkúta ààlà aládúgbò o rẹ̀.”Nígbà náà ni gbogbo ènìyàn wọ̀nyí yóò wí pé, “Àmín!”

Deutarónómì 27

Deutarónómì 27:8-24