Deutarónómì 10:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ibẹ̀ ni wọ́n ti rìn lọ sí Gúdígódà, títí dé Jótíbárà, ilẹ̀ tí o kún fún odò tí ó ń sàn.

Deutarónómì 10

Deutarónómì 10:6-17