Deutarónómì 10:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìgbà yí ni Olúwa yan àwọn ọmọ Léfì láti máa ru àpótí májẹ̀mú Olúwa, láti máa dúró níwájú Olúwa láti ṣe iṣẹ́ ìránṣẹ́, àti láti fi orúkọ Olúwa súre bí wọ́n ti ń ṣe títí di òní yìí.

Deutarónómì 10

Deutarónómì 10:7-17