Deutarónómì 10:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(Àwọn ará Ísírẹ́lì sì gbéra láti kàǹga àwọn ará a Jákánì dé Mósérà. Níbí ni Árónì kú sí, tí a sì sin ín, Élíásárì ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ bí i àlùfáà.

Deutarónómì 10

Deutarónómì 10:1-10