Deutarónómì 10:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó máa ń gbẹjọ́ aláìní baba àti opó rò, Ó fẹ́ràn àlejò, Óun fi aṣọ àti oúnjẹ fún wọn.

Deutarónómì 10

Deutarónómì 10:10-22