Deutarónómì 10:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Torí pé Olúwa Ọlọ́run yín, ni Ọlọ́run àwọn ọlọ́run àti Olúwa àwọn olúwa. Ọlọ́run alágbára, tí ó tóbi tí ó sì lẹ́rù, tí kì í ṣe ojú ṣàájú kì í sì í gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀.

Deutarónómì 10

Deutarónómì 10:16-22