Deutarónómì 10:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ gbọ́dọ̀ fẹ́ràn àwọn àlejò, torí pé ẹ̀yin pẹ̀lú ti jẹ́ àlejò rí ní Éjíbítì.

Deutarónómì 10

Deutarónómì 10:13-22