Ámósì 9:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, Ọlọ́run AlágbáraẸni ti ó fi ọwọ́ kan ìlẹ̀ náà tí ó sì yọ́, tí àwọn olùgbé inú rẹ̀ yóò sì sọ̀fọ̀Gbogbo orílẹ̀ èdè yóò si ru sókè bí ríru odò Náìlìti wọn yóò sì tẹ̀rì bí odò Éjíbítì.

Ámósì 9

Ámósì 9:1-11