Òun ni ẹni tí ó kọ́ itẹ́ rẹ̀ nínú àwọn ọ̀runti ó sì fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ sọlẹ̀ ní ilé ayéẸni ti ó pe àwọn omi òkunti ó sì tú wọn jáde si orí ilé ayé Olúwa ni orúkọ rẹ̀.