Bí wọ́n tilẹ̀ lọ sí ìgbèkùn ní iwájú àwọn ọ̀tá wọnláti ibẹ̀ ni èmi yóò ti pàṣẹ fún idà kí ó ṣá wọn pa.Èmi yóò sì tẹ ojú mi mọ́ wọn fún ìbí,kì í sì í se fún rere.”