2 Sámúẹ́lì 23:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Wọ̀nyí sì ni ọ̀rọ̀ ìkẹyìn Dáfídì.“Dáfídì ọmọ Jésè,àní ọkùnrin tí a ti gbéga,ẹni-àmì òróró Ọlọ́run Jákọ́bù,àti olórin dídùn Ísírẹ́lì wí pé:

2. “Ẹ̀mí Olúwa sọ ọ̀rọ̀ nípa mi,ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì ń bẹ ní ahọ́n mi.

2 Sámúẹ́lì 23