2 Sámúẹ́lì 24:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbínú Olúwa sì ru sí Ísírẹ́lì, ó sì ti Dáfídì sí wọn, pé, “Lọ ka iye Ísírẹ́lì àti Júdà!”

2 Sámúẹ́lì 24

2 Sámúẹ́lì 24:1-4