2 Sámúẹ́lì 22:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni ilé-ìṣọ́ ìgbàlà fún ọba rẹ̀;ó sì fi àánú hàn fún ẹni-àmì-òróró rẹ̀,fún Dáfídì, àti fún irú-ọmọ rẹ̀ títí láéláé.”

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:42-51