2 Sámúẹ́lì 23:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ̀mí Olúwa sọ ọ̀rọ̀ nípa mi,ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì ń bẹ ní ahọ́n mi.

2 Sámúẹ́lì 23

2 Sámúẹ́lì 23:1-7