2 Sámúẹ́lì 14:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Kí o sì tọ ọba wá, kí o sọ fún un gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ yìí.” Jóábù sì fi ọ̀rọ̀ sí lẹ́nu.

4. Nígbà tí obìnrin àrá Tékóà sì ń fẹ́ sọ̀rọ̀ fún ọba, ó wólẹ, ó dojúbolẹ̀, o sí bu ọlá fún un, o sì wí pé, “Ọba, gbà mi.”

5. Ọba sì bi í léèrè pé, “Kin ni o ṣe ọ́?”Òun sì dáhùn wí pé, “Nítòótọ́ opó ni èmi ń ṣe, ọkọ mi sì kú.

2 Sámúẹ́lì 14