2 Sámúẹ́lì 14:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì bi í léèrè pé, “Kin ni o ṣe ọ́?”Òun sì dáhùn wí pé, “Nítòótọ́ opó ni èmi ń ṣe, ọkọ mi sì kú.

2 Sámúẹ́lì 14

2 Sámúẹ́lì 14:1-9