2 Sámúẹ́lì 15:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yin èyí náà, Ábúsálómù sì pèṣè kẹ̀kẹ́ àti ẹsin fún ara rẹ̀, àti àádọ́ta ọmọkùnrin tí yóò máa sáré níwájú rẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 15

2 Sámúẹ́lì 15:1-6