2 Sámúẹ́lì 13:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn Dáfídì ọba sì fà gidigidi sí Ábúsálómù: nítorí tí ó tí gba ìpẹ̀ ní ti Ámúnónì: ó sáà ti kú.

2 Sámúẹ́lì 13

2 Sámúẹ́lì 13:30-39