1 Kíróníkà 26:1-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Àwọn ìpín tí àwọn olùtọ́jú ẹnu ọ̀nà:Láti ọ̀dọ̀ Kórà: Méṣélémíò ọmọ Kórè, ọ̀kan lára àwọn ọmọ Áṣáfì.

2. Méṣélémíà ní àwọn ọmọkùnrin:Ṣékáríáyà àkọ́bí,Jédíáélì ẹlẹ́ẹ̀kejì,Ṣébádíáyà ẹlẹ́ẹ̀kẹta,Játiníẹ́lì ẹlẹ́ẹ̀kẹ́rin,

3. Élámù ẹlẹ́ẹ̀kaàrún,Jehóhánánì ẹlẹ́ẹ̀kẹfààti Eliéhóémáì ẹlẹ́ẹ̀keje.

4. Obedi-Édómù ni àwọn ọmọkùnrin pẹ̀lú:Ṣémáíà àkọ́bí,Jéhóṣábádì ẹlẹ́ẹ̀kejì,Jóà ẹlẹ́ẹ̀kẹta,Ṣákárì ẹlẹ́ẹ̀kẹrin,Nétanélì ẹlẹ́ẹ̀kaàrún,

5. Ámíélì ẹ̀kẹfà,Ísákárì ẹ̀kejeàti péúlétaì ẹ̀kẹjọ(Nítorí tí Ọlọ́run ti bùkún Óbédì Édómù).

1 Kíróníkà 26