1 Kíróníkà 26:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ìpín tí àwọn olùtọ́jú ẹnu ọ̀nà:Láti ọ̀dọ̀ Kórà: Méṣélémíò ọmọ Kórè, ọ̀kan lára àwọn ọmọ Áṣáfì.

1 Kíróníkà 26

1 Kíróníkà 26:1-5