1 Kíróníkà 26:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Méṣélémíà ní àwọn ọmọkùnrin:Ṣékáríáyà àkọ́bí,Jédíáélì ẹlẹ́ẹ̀kejì,Ṣébádíáyà ẹlẹ́ẹ̀kẹta,Játiníẹ́lì ẹlẹ́ẹ̀kẹ́rin,

1 Kíróníkà 26

1 Kíróníkà 26:1-5