1 Kíróníkà 26:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obedi-Édómù ni àwọn ọmọkùnrin pẹ̀lú:Ṣémáíà àkọ́bí,Jéhóṣábádì ẹlẹ́ẹ̀kejì,Jóà ẹlẹ́ẹ̀kẹta,Ṣákárì ẹlẹ́ẹ̀kẹrin,Nétanélì ẹlẹ́ẹ̀kaàrún,

1 Kíróníkà 26

1 Kíróníkà 26:1-7