Sáàmù 90:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yí ènìyàn padà sí erùpẹ̀,wí pé “padà sí erùpẹ̀, ìwọ ọmọ ènìyàn”.

Sáàmù 90

Sáàmù 90:1-8