Sáàmù 90:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé ìgbà tí ẹgbẹ̀rún ọdún bá kọjá lójú Rẹ,bí àná ni ó rí, bí ìgbà ìṣọ́ kan lóru.

Sáàmù 90

Sáàmù 90:1-6