Sáàmù 9:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lù wọ́n pẹ̀lú ìpayà, Olúwa;jẹ́ kí àwọn orílẹ̀ èdè mọ̀ pé ènìyàn lásán ni wọ́n. Sela

Sáàmù 9

Sáàmù 9:19-20