Sáàmù 9:19-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Dìde, Olúwa, má ṣe jẹ́ kí ènìyàn borí;Jẹ́ kí a ṣe ìdájọ́ àwọn orílẹ̀ èdè ni iwájú Rẹ.

20. Lù wọ́n pẹ̀lú ìpayà, Olúwa;jẹ́ kí àwọn orílẹ̀ èdè mọ̀ pé ènìyàn lásán ni wọ́n. Sela

Sáàmù 9