Sáàmù 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èé ha ti ṣe, Olúwa, tí ìwọ fi dúró ní òkè réré?È ha ti ṣe tí ìwọ fi ara Rẹ pamọ́ ní ìgbà ìpọ́njú?

Sáàmù 10

Sáàmù 10:1-11